Articles liés à Ọlọrun ni Olùpamọ́ Rẹ

Ọlọrun ni Olùpamọ́ Rẹ - Couverture souple

Akinyemi, Philip O

 
9780997923865: Ọlọrun ni Olùpamọ́ Rẹ

Synopsis

Awọn itan Bibeli ti inu iwe yi yio jẹ iranwọ fun awọn ọmọde lati mọ pe (ranti pe) ohunkohun yo wu ti ńsẹlẹ ninu aiye wọn tabi ni ayika wọn, Ọlọrun ntọju, bẹni O si ńsọ wọn lọsan ati loru. Ko dabi awọn obi wa, Ọlọrun ki i sun tabi ko sarẹ. Ọlọrun si mọ ọjọ waju. O jẹ olododo ati Ẹniti ńpa adehun Rẹ mọ.

Les informations fournies dans la section « Synopsis » peuvent faire référence à une autre édition de ce titre.

À propos de l'auteur

Dr. Philip O. Akinyẹmi jẹ ọmọ ẹgbẹ awọn ti ńkọ iwe ati aworan fun awọn ọmọde ti ańpe ni (Society of Children's Book Writers and Illustrators - SCBWI). O ńgbe ni ipinlẹ Georgia ti America. Ninu awọn iwe ti o kọ ni "The Holy Spirit and Knowing God." Ẹdun ọkan rẹ ni lati mọ Ọlọrun timọtimọ ati lati jẹ ki awọn enia mọ ọ daradara.

Les informations fournies dans la section « A propos du livre » peuvent faire référence à une autre édition de ce titre.